Òsán pόn ò sán èko ; oòrún kan àtàri o ò jè àmàlà ; àlejo-ό wá bà o ni ìyètàrí oòrùn o ò rí ǹkan fún un ; o ní « Ǹjè njè ò níí tè lόwό è báyìí ? O ò tíì tè lόwό ara è, ká tό sèsè wá wipé o ό tèé lόwό elòmíràn tàbí o ò níí tè ?
|
lun. | mar. | mer. | jeu. | ven. | sam. | dim. |
---|---|---|---|---|---|---|
1 | 2 | 3 | ||||
4 | 5 | 6 | 7 | 8 | 9 | 10 |
11 | 12 | 13 | 14 | 15 | 16 | 17 |
18 | 19 | 20 | 21 | 22 | 23 | 24 |
25 | 26 | 27 | 28 | 29 | 30 |
Commentaires