Jazz ati Afro Cuban
Mo ki gbogbo awa ololufe Jazz. E ku ifarada. Pupo ninu awon eniyan wa ro wipe Fuji, Juju , Highlife, ati awon Orin ibile nikan ni awon Yoruba n'ma gabadun ni oro igbesi aiye won. Oro yii ko ri be.
Laye igba ominira awon iya ati baba wa Miles Davis, Duke Ellington, Arsenio Rodriguez, Celia Cruz, Fela Kuti wa ninu awon ona ti awa nife si. E ri wipe oruko ti mo pe gbogbo won ni ona, onagoruwa. Onisona wa osere de wa. Ti osho (oko awon Iya ) ba wa ninu awon ti won ba ngbe orin jazz jade Wayne Shorter ni oruko re maa je. Abi ki leni mo wi. Awon awo re ti o ma mu inu mi dun ni Juju, Soothsayers, The All seeing eye.
Ni aye ode oni awon Joshua Redman, Nacao Zumbi, Jorge Ben, Roy Hargrove, Chucho Valdes, Irakere ni awa ma n' gbadun. O ye ki awon ile ishe irohin ati amohunmaworan wa ma se awon eto jazz ati afro cuban bi won nti nse ti awon oni fuji ati juju. Ebe ni a nbe o
...
Copyright, Blaise APLOGAN, 2009,© Bienvenu sur Babilown
Tout copier/collage de cet article sur un autre site, blog ou forum, etc.. doit en mentionner et l’origine et l’auteur sous peine d’être en infraction.
Commentaires
Vous pouvez suivre cette conversation en vous abonnant au flux des commentaires de cette note.