Ikan ninu awon alejo ti o ma nwa ki wa lori ile jankariwo yi bere lowo mi wipe kilose ti mo lo da Ile ise sile ni ilu Ghana. Sasa ni Eni ti o ba lo si Ile yi ti o ni feran re.
Awon eniyan ti o ngbe ni ilu yi fa mi mora. Pupo ninu Ede ati asa awon orile ede ti o wa ni ilu Ghana bi awon Asante, Fanti, Ga ni o jo ti awa Anago (Yoruba). Alaafia ati ife wa yika agbegbe ilu.
Awon Olaju si po nibe. Eyi se pataaki fun mi nitori pe oro aimo ni o Npa wa lo ni Ile Africa.
Asho L'eniyan
Omi Titun Tiru--Ayinla Omowura
Gilberto Gil- Baba Alapala
Bro. Teesaid...
-
Otito lo so. Ko siro nibe. Ikorira ati iwa jibiti ti o wa ni orile ede wa je ohun ti o nfa idagbasoke ile wa sehin.
Ki Olorun Eledumare ki o ran Nigeria lowo.
Aje a wa O!5:53 AM
- Anonymous said...
-
Orile ede Nigeria na dara. E je ka to awon odo wa si ona. E je ka fi owo ara wa tu ilu wa se.
8:44 PM
-
Onibudosaid...
-
Bi aba se pe igba wa ni gbo eniyan bawa pe. ilosiwaju orile ede Nigeria di owo wa. Ko si ilu ti ko ni alebu ni ara, ki Eleduumare fi ona ati oye to wa si ono. Ko si nkan to o buru nipa ati da ilese sile ni ibi kibi sugbon, Oro sunuku, oju Sunuku ni afi wo.
5:14 AM
- Iyaetosaid...
-
Hmm Omo obokun. Awon araa Ghana tun ilu won se ni ose dara. Sugbon ki a ma puro, Ghana je ilu kan ti o dara lopo lopo moti pinu lati lo si ilu naa. Mo ni awon ore kan ti own ti lo tedo si Kumasi lati ilu Oba. Osi wun mi lopo lopo lati lo si Accra naa. Awon omo Ghana ti mo ni l'ore ni ibi ti mo wa se omoluabi. Won feran mi mosi feran won naa. "Meda wasi"( otumo si e se pupo).
6:27 PM
-
30+said...
-
Omi inu nkan mi fun gbogbo iroyin rere ti mo ngbo nipa ile Ghana. Nitori o nmu mi ranti aleebu ti o ba orile ede mi Nigeria ja.
Mo ti tile gbo wipe opo lati Nigeria nlo si Ghana fun isimi ranpe la lai kobi ara si ilu oyinbo nitori owo oko ofurufu. Opo si tun lo tedo si be pelu.
Tani ni yio wa duro lati tun orile ede mi se. Emi tikalara ti na papa bora bayi, moti mu ibujoko mi si orile ede oyinbo.
Iyaeto, eyin gbo ede won.
Aje wipe ki a ma fi adura ranse loku si Nigeria loku7:41 AM
- Girliesaid...
-
erm. yoruba mi o jino de nu!!!
sugbon mo ti ka die ninu blog yin.
E ku ise!!!!8:08 AM
- Anonymous said...
-
oga o fun blog yi o!!!
e da kun ejo o, e je kin saa re so geesi kan...
this blog is awesome..sure i read it slower but hey i'mtripped...e ma binu , e ku ise daada
aya olakunle8:29 AM
- shareinfoline said...
- shareinfoline technical analysts keeps there eyes on this bullish Indian stock market to provide best intraday and long term share market calls daily. Our trading tips covers NSE and BSE .
Check gainers,losers ,news, IPO ,Free tips,trading tricks and all new mutual funds .
Regards www.shareinfoline.com -
Copyright, Blaise APLOGAN, 2010,© Bienvenu sur Babilown
Tout copier/collage de cet article sur un autre site, blog ou forum, etc.. doit en mentionner et l’origine et l’auteur sous peine d’être en infraction.
Commentaires